Jeremáyà 3:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbé ojú rẹ sí ibi gíga aláìléso kí o sì wò óibi kan ha wà tí a kò ti fi agbára mú ọ?Ní ojú ọ̀nà, ìwọ jókòó de àwọn olólùfẹ́,o jókòó bí i àwọn alárìnkiri nínú ihà.O ti ba ilẹ̀ náà jẹ́pẹ̀lú ìwà panṣágà àti ìwà búburú rẹ.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:1-12