Jeremáyà 3:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi fúnra mi sọ wí pé,“ ‘Báwo ni inú mi yóò ti dùn tó, kí èmi kí ó tọ́ ọ bí ọmọkùnrinkí n sì fún ọ ní ilẹ̀ tí ó tó.’Mo rò pé ìwọ yóò pè mí ní ‘Baba mi’o kò sì ní ṣàì tọ̀ mí lẹ́yìn.

Jeremáyà 3

Jeremáyà 3:10-22