Jeremáyà 29:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ṣẹlẹ̀ ní ẹ̀yìn ìṣèjọba Jéhóíákímù àti ayaba àti ìwẹ̀fà pẹ̀lú àwọn olórí Júdà àti Jérúsálẹ́mù, àwọn gbẹ́nà gbẹ́nà àti àwọn olùyàwòrán tí wọ́n lọ ṣe àtìpó láti Jérúsálẹ́mù.

Jeremáyà 29

Jeremáyà 29:1-9