Jeremáyà 28:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láàrin ọdún méjì, mà á mú gbogbo ohun èlò tí Ọba Nebukadinésárì; Ọba Bábílónì kó kúrò ní ilé Olúwa tí ó sì kó lọ sí Bábílónì padà wá.

Jeremáyà 28

Jeremáyà 28:2-9