Jeremáyà 28:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ sọ fún Hananáyà, ‘Èyí ni ohun tí Olúwa wí: Ìwọ ti wó àjàgà onígi, ṣùgbọ́n ní àyè wọn, wà á bá àjàgà onírin.

Jeremáyà 28

Jeremáyà 28:5-17