Jeremáyà 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìṣèjọba Sedekáyà ọmọ Jòsáyà Ọba Júdà, ọ̀rọ̀ yìí tọ Jeremáyà wá láti ọ̀dọ̀ Olúwa:

Jeremáyà 27

Jeremáyà 27:1-3