Jeremáyà 26:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ mọ̀ dájú pé tí ẹ bá pa mí, ẹ ó mú ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ wá sórí ara yín, sórí orílẹ̀ èdè yìí àti àwọn olùgbé inú rẹ̀; nítorí pé nítòótọ́ ni Olúwa ti rán mi láti sọ ọ̀rọ̀ yìí fún un yín.”

Jeremáyà 26

Jeremáyà 26:14-18