Jeremáyà 25:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe tọ àwọn Ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn láti sìn wọ́n tàbí bọ wọ́n; ẹ má ṣe mú inú bí mi pẹ̀lú ohun tí ẹ ti fi ọwọ́ yín ṣe. Nígbà náà ni Èmi kò ní ṣe yín ní ibi.”

Jeremáyà 25

Jeremáyà 25:1-9