Jeremáyà 25:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́ igbe àwọn olùsọ́ àgùntàn,àti ìpohùnréré ẹkún àwọn olóríagbo ẹran; nítorí pé Olúwa ń pa pápá oko tútù wọn run.

Jeremáyà 25

Jeremáyà 25:31-38