Jeremáyà 25:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ké, kí ẹ sì pohùnréré ẹkúnẹ̀yin olùsọ́ àgùntàn, ẹ yí nínú eruku,ẹ̀yin olùdarí agbo ẹran,nítorí pé ọjọ́ àti pa yín ti dé,ẹ̀yin ó sì ṣubú bí ohun èlò iyebíye.

Jeremáyà 25

Jeremáyà 25:24-38