Jeremáyà 25:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti gbogbo àwọn ènìyàn àjòjì tí ó wà níbẹ̀; gbogbo àwọn Ọba Húsì, gbogbo àwọn Ọba Fílístínì, gbogbo àwọn ti Áṣíkélónì, Gásà, Ékírónì àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ó kù sí Áṣídódì.

Jeremáyà 25

Jeremáyà 25:17-28