Jeremáyà 25:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jérúsálẹ́mù àti àwọn ìlú Júdà, àwọn Ọba wọn pẹ̀lú àwọn aláṣẹ wọn, láti sọ wọ́n di ohun ìparun, ohun ẹ̀rù, ẹ̀sìn àti ègún, gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti rí lónìí yìí.

Jeremáyà 25

Jeremáyà 25:16-21