Jeremáyà 24:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Agbọ̀n kan ni èṣo ọ̀pọ̀tọ́ tí ó dára bí èyí tí ó tètè pọ́n; èkejì sì ní èṣo ọ̀pọ̀tọ́ tí ó burú rékọjá tí kò sì le è ṣe é jẹ

Jeremáyà 24

Jeremáyà 24:1-4