Jeremáyà 23:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ti àwọn wòlíì èké:Ọkàn mi ti bàjẹ́ nínú mi,gbogbo egungun mi ni ó wárìrì.Èmi dàbí ọ̀mùtí ènìyàn,bí ọkùnrin tí ọtí wáìnì ń pa;nítorí Olúwa àti àwọn ọ̀rọ̀ mímọ́ rẹ̀.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:4-15