Jeremáyà 23:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n rò wí pé àlá tí wọ́n ń sọ fún ara wọn yóò mú kí àwọn ènìyàn mi gbàgbé orúkọ mi, gẹ́gẹ́ bí àwọn baba wọn ṣe gbàgbé orúkọ mi nípa sísin òrìṣà Báálì.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:22-31