Jeremáyà 23:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, afẹ́fẹ́ Olúwa yóò tú jádepẹ̀lú ìbínú àfẹ́yíká ìjì yóò fẹ́ síorí àwọn olùṣe búburú.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:10-28