Jeremáyà 23:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Láàrin àwọn wòlíì Saáríà,Èmi rí ohun tí ń lé ni sá:Wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ lórúkọ Báálìwọ́n sì mú Ísírẹ́lì ènìyàn mi sìnà.

Jeremáyà 23

Jeremáyà 23:10-16