Jeremáyà 22:27-30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

27. Ẹ̀yin kì yóò padà sí ilẹ̀ tí ẹ̀yin fẹ́ mọ́ láéláé.”

28. Ǹjẹ́ Jéhóíákínì ẹni ẹ̀gàn yàtọ̀ sí ìkòkò òfìfo,ohun èlò tí ẹnìkan kò fẹ́?Èéṣe tí a fi òun àti àwọn ọmọ rẹ̀ sókèsí ilẹ̀ tí wọn kò mọ̀.

29. Ìwọ ilẹ̀, ilẹ̀, ilẹ̀,gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa!

30. Báyìí ni Olúwa wí:“Kọ àkọsílẹ̀ ọkùnrin yìí sínú ìwé gẹ́gẹ́ bí aláìlọ́mọ,ẹni tí kì yóò ṣe rere ní ọjọ́ ayé rẹ̀;nítorí ọ̀kan nínú irú ọmọ rẹ̀ kì yóò ṣe rere,èyíkéyìí wọn kì yóò jókòó lórí ìtẹ́ Dáfídìtàbí jọba ní Júdà mọ́.”

Jeremáyà 22