Jeremáyà 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa ìwọ Ọba Júdà, tí ó jókòó ní Ìtẹ́ Dáfídì, ìwọ, àwọn ènìyàn rẹ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ, tí ó wọlé láti ẹnu ibodè wọ̀nyí.

Jeremáyà 22

Jeremáyà 22:1-11