Jeremáyà 22:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí pé, ‘Èmi ó kọ́ ààfin ńlá fún ara miàwọn yàrá òkè tí ó fẹ̀,ojú fèrèsé rẹ̀ yóò tóbi.’A ó sì fi igi kédárì bò ó,a ó fi ohun aláwọ̀ pupa ṣe é ní ọ̀ṣọ́.

Jeremáyà 22

Jeremáyà 22:12-18