Jeremáyà 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Wádìí lọ́wọ́ Olúwa fún wa nítorí Nebukadinésárì Ọba Bábílónì ń kọlù wá. Bóyá Olúwa yóò ṣe ìyanu fún wa gẹ́gẹ́ bí ti àtẹ̀yìnwá, kí ó sì yípadà kúrò lọ́dọ̀ wa.”

Jeremáyà 21

Jeremáyà 21:1-7