Jeremáyà 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti pinnu láti jẹ ìlú yìí níyà, ni Olúwa wí. A ó sì gbé e fún Ọba Bábílónì, yóò sì run ún pẹ̀lú iná.’

Jeremáyà 21

Jeremáyà 21:2-14