Jeremáyà 20:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n bí mo bá sọ pé, “Èmi kì yóò dárúkọ rẹtàbí sọ nípa orúkọ rẹ̀ mọ́,ọ̀rọ̀ rẹ̀ ń bẹ bi iná tí ń jó nínú mití a sé nínú egungun miAgara dá mi ní inú minítòótọ́ èmi kò lè ṣe é.

Jeremáyà 20

Jeremáyà 20:1-12