Jeremáyà 20:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó mú kí wọ́n lù ú, kí wọ́n sì fi sínú túbú tí ó wà ní òkè ẹnu ọ̀nà ti Bẹ́ńjámínì ní Tẹ́ḿpìlì Olúwa.

Jeremáyà 20

Jeremáyà 20:1-4