Jeremáyà 20:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ègbé ni fún ọkùnrin tí ó mú ìròyìn wá fún baba mi,Tí ó mú kí ó yọ̀, tí ó sì sọ wí pé,“A bí ọmọ kan fún ọ—ọmọkùnrin!”

Jeremáyà 20

Jeremáyà 20:7-18