Jeremáyà 20:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọrin sí Olúwa!Fi ìyìn fún Olúwa!Ó gba ẹ̀mí àwọn aláìnílọ́wọ́ àwọn ẹni búburú.

Jeremáyà 20

Jeremáyà 20:7-18