Jeremáyà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo mú yín wá sí ilẹ̀ ọlọ́ràá láti máajẹ èso ibẹ̀ àti ọrọ̀ rẹ̀, ẹ̀yin sì wá, ẹ sìba ilẹ̀ náà jẹ́, ẹ sì mú àwọnohun ogún mi di ohun ìríra.

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:4-12