Báyìí ni Olúwa wí:“Irú àwọn àìṣedédé wo ni baba yín rí nínú mi?Tí wọ́n fi jìnnà sími? Wọ́n tẹ̀léàwọn òrìṣà tí kò jámọ́ nǹkan kanàwọn fúnra wọn sì jẹ́ ènìyàn yẹpẹrẹ.