Jeremáyà 2:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ló dé tí o ṣe wá lọ Éjíbítìláti lọ mu omi ní Síhórì?Kí ló dé tí o sì fi lọ sí Àsíríàláti lọ mu omi ni odò Yúfúrátè náà

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:15-27