Jeremáyà 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwọn ènìyàn mi ti dẹ́sẹ̀, méjìWọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, Èmiorísun omi ìyè, wọ́n sì tiwọ àmù, àmù fífọ́ tí kò lègba omi dúró.

Jeremáyà 2

Jeremáyà 2:10-15