Jeremáyà 19:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà sọ́ra ọjọ́ ń bọ̀ ni Olúwa wí nígbà tí àwọn ènìyàn tí a kì yóò pe ibí ní Tófẹ́tì tàbí ọmọ Hininómù, ṣùgbọ́n Àfonífojì ìpakúpa.

Jeremáyà 19

Jeremáyà 19:1-8