Jeremáyà 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí wọ́n ti gbàgbé mi, wọ́n sì ti sọ ibí di ilé fún òrìṣà àjòjì; wọ́n ti sun ẹbọ nínú rẹ̀ fún òrìṣà tí àwọn baba wọn tàbí tí Ọba Júdà kò mọ̀ rí, wọ́n ti fi ẹ̀jẹ̀ aláìsẹ̀ kún ilẹ̀ yìí.

Jeremáyà 19

Jeremáyà 19:1-12