Jeremáyà 19:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà ni ìwọ yóò fọ́ ìkòkò náà ní oju àwọn tí ó bá ọ lọ.

Jeremáyà 19

Jeremáyà 19:1-15