Jeremáyà 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí orílẹ̀ èdè ti mo kìlọ̀ fún bá yípadà kúrò nínú ìwà búburú wọn, nígbà náà ni Èmi yóò yí ọkàn mi padà níbi àjálù tí mo ti rò láti ṣe sí wọn.

Jeremáyà 18

Jeremáyà 18:1-18