Jeremáyà 18:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ wọn yóò wà lásán yóò sì dinǹkan ẹ̀gàn títí láé. Gbogboàwọn tí ó ń kọjá yóò bẹ̀rù, wọnyóò sì mi orí wọn.

Jeremáyà 18

Jeremáyà 18:14-22