Jeremáyà 17:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ipaṣẹ̀ àìṣedéédé yín ni ẹ̀yinyóò ti sọ ogún tí mo fún un yín nù.Èmi yóò fi yín fún ọ̀tá yínbí ẹrú ní ilẹ̀ tí ẹ̀yin kò mọ̀; nítoríẹ̀yin ti mú inú bí mi, èyí tí yóò sì wà títí ayé.”

Jeremáyà 17

Jeremáyà 17:1-12