Jeremáyà 17:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àparò tó pa ẹyin tí kò yé niọmọ ènìyàn tí ó kó ọrọ̀ jọ niọ̀nà àìsòdodo. Yóò di ẹni ìkọ̀sílẹ̀ní agbede-méjì ayé rẹ̀, àti níòpin rẹ̀ yóò wá di aṣiwèrè.

Jeremáyà 17

Jeremáyà 17:9-13