Jeremáyà 16:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti ẹni ńlá àti kékeré ni yóò ṣègbé ní ilẹ̀ yìí, wọn kò ní sin wọ́n tàbí sọ̀fọ̀ wọn, bẹ́ẹ̀ ni kò sí ẹni tí yóò fá irun orí wọn nítorí wọn.

Jeremáyà 16

Jeremáyà 16:1-16