Jeremáyà 16:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé àwọn ènìyàn lè dá Ọlọ́runfún ara wọn bí? Bẹ́ẹ̀ ni,ṣùgbọ́n àwọn wọ̀nyí kì í ṣe Ọlọ́run.”

Jeremáyà 16

Jeremáyà 16:12-20