Jeremáyà 15:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

N ó sọ wọ́n di ẹni ìkórìíra níwájú gbogbo ìjọba ayé torí ohun tí Mánásè ọmọ Heṣekáyà Ọba àwọn Júdà ṣe ní Jérúsálẹ́mù.

Jeremáyà 15

Jeremáyà 15:1-9