Jeremáyà 15:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sọ pé,“Dájúdájú èmi ò dá ọ sí fún ìdí kan pàtó.Dájúdájú mo mú kí àwọn ọ̀tá rẹtẹríba níwájú rẹ nígbà ibi àti ipọ́njú.

Jeremáyà 15

Jeremáyà 15:4-16