Jeremáyà 14:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ dúró lórí òkè òfìfowọ́n sì ń mí hẹlẹhẹlẹ bí ìkokòojú wọn kò rírannítorí pé kò sí koríko jíjẹ.”

Jeremáyà 14

Jeremáyà 14:1-12