Jeremáyà 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, a jẹ́wọ́ ìwà ibi waàti àìṣedédé àwọn baba wa;lóòótọ́ ni a ti ṣẹ̀ sí ọ.

Jeremáyà 14

Jeremáyà 14:16-22