Jeremáyà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Júdà káàánú,àwọn ìlú rẹ̀ kérorawọ́n pohùnréré ẹkún fún ilẹ̀ wọn,igbe wọn sì gòkè lọ láti Jérúsálẹ́mù.

Jeremáyà 14

Jeremáyà 14:1-8