Jeremáyà 13:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. N ó sí aṣọ lójú rẹkí ẹ̀sín rẹ le hàn síta

27. ìwà àgbèrè àti ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́,àìlójútì aṣẹ́wó rẹ!Mo ti rí ìwà ìkórìíra rẹlórí òkè àti ní pápá.Ègbé ni fún ọ ìwọ Jérúsálẹ́mù!Yóò ti pẹ́ tó tí o ó fi máa wà ní àìmọ́?”

Jeremáyà 13