Jeremáyà 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìní kò ha ti dàbíẹyẹ kanna-kánnátí àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ dòyì kọ tí wọ́n sì kọjú ìjà sí i?Lọ kí o lọ ṣe àkójọ gbogbo àwọn ẹranko búburú,kó wọn wá láti wá parun.

Jeremáyà 12

Jeremáyà 12:6-12