Jeremáyà 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ ogun sọ pé, ‘Èmi yóò fìyà jẹ wọ́n, àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin wọn yóò tipasẹ̀ idà kú, ìyàn yóò pa àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin wọn.

Jeremáyà 11

Jeremáyà 11:21-23