Jeremáyà 11:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun tí ó dá ọ ti kéde ibi sí ọ, nítorí ilé Ísírẹ́lì àti Júdà ti ṣe ohun ibi, wọ́n sì ti mú inú bí mi, wọ́n ti ru ìbínú mi sókè nípa sísun tùràrí fún Báálì.

Jeremáyà 11

Jeremáyà 11:15-18