Jeremáyà 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tú ìbínú rẹ síta sórí àwọn orílẹ̀ èdètí kò mọ̀ ọ́, sórí àwọn ènìyàntí wọn kò pe orúkọ rẹ. Nítorí péwọ́n ti jẹ Jákọ́bù run, wọ́n ti jẹ ẹ́run pátapáta, wọ́n sì ti ba ilẹ̀ ibùgbé rẹ̀ jẹ́.

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:24-25