Jeremáyà 10:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi mọ̀ Olúwa wí pé ayé ènìyàn kì íṣe ti ara rẹ̀, kì í ṣe fún ènìyàn láti gbe igbésẹ ara rẹ̀.

Jeremáyà 10

Jeremáyà 10:18-25